Red de Bibliotecas Virtuales de Ciencias Sociales en
América Latina y el Caribe

logo CLACSO

Por favor, use este identificador para citar o enlazar este ítem: https://biblioteca-repositorio.clacso.edu.ar/handle/CLACSO/167445
Título : Igioṣè no reino de obaràyí: Uma etnografia acerca da presença do baobá no Ilê axé opô aganju, Bahia
Autor : REESINK, Edwin Boudewijn
REESINK, Mísia Lins Vieira
http://buscatextual.cnpq.br/buscatextual/busca.do
http://buscatextual.cnpq.br/buscatextual/busca.do
Palabras clave : Candomblé. Baobá. Ilê Axé Opô Aganju. África soteropolitana;Candomblé. Igi Osè. Ilê Axé Opô Aganju. ilè Afirika-Bahia;Baobá.
Editorial : Universidade Federal de Pernambuco
UFPE
Brasil
Programa de Pos Graduacao em Antropologia
Descripción : Esta dissertação tem por objetivo etnografar a presença de Igi Oṣè, conhecida entre nós como baobá (Adansonia digitata), no Ilê Axé Opô Aganju, Lauro de Freitas, BA. Liderado por Balbino Daniel de Paula, Obaràyí, o Aganju foi um dos contemplados pelo Projeto (Im)Plantando Morada dos Ancestrais em Salvador, CEAO-UFBA/SEMUR (2006), que objetivou a disseminação dessa árvore prioritariamente nos jardins sagrados baianos, a partir de mudas transportadas do Recife, desde 2005, para a capital baiana. Até então, os únicos registros dessa espécie da flora africana no arboreto urbano de Salvador se encontravam restritos ao Largo 2 de julho (Praça do Campo Grande) e ao Largo de Nazaré (Praça Almeida Couto) e, no Candomblé, apenas ao Ilê Axé Alabaxé, em Maragogipe, onde a árvore foi plantada em 24 de junho de 1993. O trabalho de campo foi realizado de setembro de 2015 a fevereiro de 2016. No Aganju, Igi Oṣè passa a ser associado ao vodun ao qual se atribui a primazia do culto às árvores na nação Jeje (PARÉS, 2006), a evidenciar absorções que ocorrem entre as diversas nações do Candomblé na Bahia. Ainda desconhecido pela maioria da comunidade religiosa, o acesso aos loci botânico e – mesmo que incipiente - litúrgico do Candomblé propiciado por esses sujeitos ao baobá ratifica a criativa tradição de (re)invenção religiosa visando à manutenção da África soteropolitana por essas comunidades que demonstram prestígio político ao atuarem de modo a serem contempladas por ações acadêmicas e políticas.
Èròngbà àpilèko yìí ni láti se ìwádìí ní òrínkínniwín lórí Igi Osè ti ó gbajúgbajàs láàrín wa tí òpòlopò si mo orúkò rè gégé bíi baobá (Adansonia digitata) èyi tí ó wà ní gbàgede Ilé Àse Òpó Aganjú ni Lauro de Freitas, Bahia lábé àkóso alàgbà Balbino Daniel de Paula, Obaràyí, fún àkànse isé ìwádìi lábé ètò tí a pe àkolé rè ni Gbígbín Ibùgbé fún awon Òrìsà ni ilú Salvador labe àkóso ètò àjosepò laarin CEAO-UFBA ati SEMUR (2006). Kókó èròngba ètò náà ni lati se ìfilólè igi-osè yí nipa gbigbin awon pòpórò igi-osè náa ti a mú lati ilú Recife wa si ilè Bahia ni odun 2005. Saájú àkókò yìí, àkosílè tí a ríkà ni wípé eyo méjì péré ni irúfé èyà igi-osè àbáláyé ti ilè Áfíríkà tí a lè ri ní agbègbé ìlú Salvador: òkan ni gbágede ogbà ti a mò sí dois de Julho (Largo Campo Grande) nígbàtí èkejì si wà ni gbàgede ojúde tí a mò sí Praça Almeida Couto ni adúgbò Nazaré. Bákannáà, ákosílè fi yéwa pé ni àwùjo awon olírìsà (Candomblé), awon olùsìn vodum ní ìfokànsìn púpò si igi-osè nítorípé láarin awon olóòsà vodúm, igiosè jé igi pàtàkì fun awon ìran aláwòdúdú ti a mò si jeje ni ilè Basíì (PARÉS, 2006). Lilo tí awon olórísà candomblé yókù náà nlo igi-osè yìí bayìí fihan wipe àjosepò tó gúnmó ni o wà láàrín gbogbo awon elésìn àbálayé orìsà, vodum ati nkisi ti o parapò di Candomblé ni ilè Bahia ti o si tan kálè de gbogbo ilè Bàsíì. Biótilèjépé òpolópò awon olórìsà elésìn àbáláyé ìran ènìyàn dúdú ni Ilè Bàsíì ni kò dá ojúlówó igi-osè mò dúnjú, wíwà tí irúfé igi ti won npe ni baobâ wà ni àwùjo Bahia báyìí gegebi igi ìsòyè ni awon ibi tuntun ti a sèsè fi wón lólè si yìí gégébíi loci botanico fihan ipa tí ifokànsìn tí o múnámúnà tí o sí so ilè Bahia di gbajúgbajà láàrín awujo awon oloosa lágbàáyé se jé elérìí sí ifé tí awon babanla awon ènìyàn dúdú tí won ko jékì èsìn ati ìse ìsèmbáyé ilè Áfíríkà parun ní ilè Améríkà èyí tí o sì fá gbígbajúmò tí èsìn Candomblè ti ilè Bahia se gbajúmo tobéègéé ti ó fi di ohun tí òpòlopò onímò ìjìnlè ati ìjoba yàn án láàyò fún isé akadá ati ètò ìfowósowópò pelú ètò ìsèlú.
URI : http://biblioteca-repositorio.clacso.edu.ar/handle/CLACSO/167445
Otros identificadores : https://repositorio.ufpe.br/handle/123456789/17998
Aparece en las colecciones: Programa de Pós Graduação em Antropologia - PPGA/UFPE - Cosecha

Ficheros en este ítem:
No hay ficheros asociados a este ítem.


Los ítems de DSpace están protegidos por copyright, con todos los derechos reservados, a menos que se indique lo contrario.